Ẹk. Jer 3:61-65 Yorùbá Bibeli (YCE)

61. Iwọ ti gbọ́ ẹ̀gan wọn, Oluwa, gbogbo èro buburu wọn si mi.

62. Ète awọn wọnni ti o dide si mi, ati ipinnu wọn si mi ni gbogbo ọjọ.

63. Kiyesi ijoko wọn ati idide wọn! emi ni orin-ẹsin wọn.

64. San ẹsan fun wọn, Oluwa, gẹgẹ bi iṣẹ ọwọ wọn!

65. Fun wọn ni ifọju ọkàn, ègun rẹ lori wọn!

Ẹk. Jer 3