Ẹk. Jer 3:59-63 Yorùbá Bibeli (YCE)

59. Oluwa, iwọ ti ri inilara mi, ṣe idajọ ọran mi!

60. Iwọ ti ri gbogbo igbẹsan wọn, gbogbo èro buburu wọn si mi.

61. Iwọ ti gbọ́ ẹ̀gan wọn, Oluwa, gbogbo èro buburu wọn si mi.

62. Ète awọn wọnni ti o dide si mi, ati ipinnu wọn si mi ni gbogbo ọjọ.

63. Kiyesi ijoko wọn ati idide wọn! emi ni orin-ẹsin wọn.

Ẹk. Jer 3