Ẹk. Jer 3:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. EMI ni ọkunrin na ti o ti ri wàhala nipa ọpa ibinu rẹ̀.

2. O ti fà mi, o si mu mi wá sinu òkunkun, kì si iṣe sinu imọlẹ.

3. Lõtọ, o yi ọwọ rẹ̀ pada si mi siwaju ati siwaju li ọjọ gbogbo.

Ẹk. Jer 3