Ẹk. Jer 2:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa ti ṣá pẹpẹ rẹ̀ tì, o ti korira ibi-mimọ́ rẹ̀, o ti fi ogiri ãfin rẹ̀ le ọwọ ọta; nwọn ti pa ariwo ninu ile Oluwa, gẹgẹ bi li ọjọ ajọ-mimọ́.

Ẹk. Jer 2

Ẹk. Jer 2:1-17