Ẹk. Jer 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa jẹ gẹgẹ bi ọta: o ti gbe Israeli mì, o ti gbe gbogbo ãfin rẹ̀ mì: o ti pa ilu olodi rẹ̀ run o si ti fi ibanujẹ lori ibanujẹ fun ọmọbinrin Juda.

Ẹk. Jer 2

Ẹk. Jer 2:1-14