Ẹk. Jer 2:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

O ti ke gbogbo iwo Israeli kuro ninu ibinu gbigbona rẹ̀: o ti fà ọwọ ọtun rẹ̀ sẹhin niwaju ọta, o si jo gẹgẹ bi ọwọ iná ninu Jakobu ti o jẹrun yikakiri.

Ẹk. Jer 2

Ẹk. Jer 2:1-5