Ẹk. Jer 2:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ewe ati arugbo dubulẹ ni ita wọnni: awọn wundia mi ati awọn ọdọmọkunrin mi ṣubu nipa idà: iwọ ti pa li ọjọ ibinu rẹ; iwọ ti pa, iwọ kò si dasi.

Ẹk. Jer 2

Ẹk. Jer 2:11-22