Ẹk. Jer 2:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dide, kigbe soke li oru ni ibẹrẹ akoko iṣọ: tú ọkàn rẹ jade gẹgẹ bi omi niwaju Oluwa: gbe ọwọ rẹ soke si i fun ẹmi awọn ọmọ wẹwẹ rẹ, ti nkulọ fun ebi ni gbogbo ori-ita.

Ẹk. Jer 2

Ẹk. Jer 2:14-22