Ẹk. Jer 2:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa ti ṣe eyi ti o ti rò; o ti mu ọrọ rẹ̀ ṣẹ ti o ti paṣẹ li ọjọ igbãni: o ti bì ṣubu, kò si dasi: o si ti mu ọta yọ̀ lori rẹ, o ti gbe iwo awọn aninilara rẹ soke.

Ẹk. Jer 2

Ẹk. Jer 2:14-19