Ẹk. Jer 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn woli rẹ ti riran ohun asan ati wère fun ọ: nwọn kò si ti fi aiṣedede rẹ hàn ọ, lati yi igbekun rẹ pada kuro; ṣugbọn nwọn ti riran ọ̀rọ-wiwo eke fun ọ ati imuniṣina.

Ẹk. Jer 2

Ẹk. Jer 2:4-20