Ẹk. Jer 1:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo ẹwà ọmọbinrin Sioni si ti lọ kuro lọdọ rẹ̀: awọn ijoye rẹ̀ dabi agbọnrin ti kò ri pápá oko tutu, nwọn si lọ laini agbara niwaju alepa nì,

Ẹk. Jer 1

Ẹk. Jer 1:2-11