Ẹk. Jer 1:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jẹ ki gbogbo ìwa-buburu wọn wá si iwaju rẹ; si ṣe si wọn, gẹgẹ bi iwọ ti ṣe si mi nitori gbogbo irekọja mi: nitori ikẹdùn mi pọ̀, ọkàn mi si rẹ̀wẹsi.

Ẹk. Jer 1

Ẹk. Jer 1:13-22