Ẹk. Jer 1:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa ti tẹ̀ gbogbo awọn akọni mi mọlẹ labẹ ẹsẹ li arin mi: On ti pe apejọ sori mi lati tẹ̀ awọn ọdọmọkunrin mi rẹ́: Oluwa ti tẹ ifunti fun wundia, ọmọbinrin Juda.

Ẹk. Jer 1

Ẹk. Jer 1:13-18