Ẹk. Jer 1:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn enia rẹ̀ kẹdùn, nwọn wá onjẹ; nwọn fi ohun daradara fun onjẹ lati tu ara wọn ninu. Wò o, Oluwa, ki o si rò! nitori emi di ẹni-ẹ̀gan.

Ẹk. Jer 1

Ẹk. Jer 1:10-17