Efe 6:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnyin ti mọ pe ohun rere kohunrere ti olukuluku ba ṣe, on na ni yio si gbà pada lọdọ Oluwa, ibã ṣe ẹrú, tabi omnira.

Efe 6

Efe 6:2-11