Efe 5:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori eyi li ọkunrin yio ṣe fi baba ati iya rẹ̀ silẹ, on o si dàpọ mọ́ aya rẹ̀, awọn mejeji a si di ara kan.

Efe 5

Efe 5:30-32