Efe 5:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ si mã rìn ni ifẹ, gẹgẹ bi Kristi pẹlu ti fẹ wa, ti o si fi ara rẹ̀ fun wa li ọrẹ ati ẹbọ fun Ọlọrun fun õrùn didun.

Efe 5

Efe 5:1-4