Efe 4:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ẹniti ọkàn wọn le rekọja, ti nwọn si ti fi ara wọn fun wọ̀bia, lati mã fi iwọra ṣiṣẹ ìwa-ẽri gbogbo.

Efe 4

Efe 4:11-27