Efe 3:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Fun emi ti o kere ju ẹniti o kere julọ ninu gbogbo awọn enia mimọ́, li a fi ore-ọfẹ yi fun, lati wasu awamáridi ọrọ̀ Kristi fun awọn Keferi;

Efe 3

Efe 3:3-12