Efe 3:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyiti a kò ti fihàn awọn ọmọ enia rí ni irandiran miran, bi a ti fi wọn hàn nisisiyi fun awọn aposteli rẹ̀ mimọ́ ati awọn woli nipa Ẹmí;

Efe 3

Efe 3:1-7