Efe 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnyin ki o le li agbara lati mọ̀ pẹlu gbogbo awọn enia mimọ́, kini ìbú, ati gigùn, ati jijìn, ati giga na jẹ,

Efe 3

Efe 3:11-19