Efe 1:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olubukún li Ọlọrun ati Baba Jesu Kristi Oluwa wa, ẹniti o ti fi gbogbo ibukún ẹmí ninu awọn ọrun bukún wa ninu Kristi:

Efe 1

Efe 1:1-11