Efe 1:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori eyi, emi pẹlu, nigbati mo ti gburó igbagbọ ti mbẹ larin nyin ninu Jesu Oluwa, ati ifẹ nyin si gbogbo awọn enia mimọ́,

Efe 1

Efe 1:9-17