Deu 7:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o máṣe bẹ̀ru wọn: ṣugbọn ki iwọ ki o ranti daradara ohun ti OLUWA Ọlọrun rẹ ṣe si Farao, ati si gbogbo Egipti;

Deu 7

Deu 7:9-22