Deu 5:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe tani mbẹ ninu gbogbo araiye ti o ti igbọ́ ohùn Ọlọrun alãye ti nsọ̀rọ lati ãrin iná wá, bi awa ti gbọ́, ti o si wà lãye?

Deu 5

Deu 5:24-29