Deu 4:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA yio si tú nyin ká ninu awọn orilẹ-ède, diẹ ni ẹnyin o si kù ni iye ninu awọn orilẹ-ède, nibiti OLUWA yio darí nyin si.

Deu 4

Deu 4:25-30