Deu 32:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ebi yio mu wọn gbẹ, oru gbigbona li a o fi run wọn, ati iparun kikorò; emi o si rán ehín ẹranko si wọn, pẹlu oró ohun ti nrakò ninu erupẹ.

Deu 32

Deu 32:23-29