Deu 30:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni kò sí ni ìha keji okun, ti iwọ iba fi wipe, Tani yio rekọja okun lọ fun wa, ti yio si mú u fun wa wá, ki awa ki o le gbọ́ ọ, ki a si le ṣe e?

Deu 30

Deu 30:10-17