Deu 3:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li awa gbà li ọwọ́ awọn ọba ọmọ Amori mejeji, ilẹ ti mbẹ ni ìha ẹ̀bá Jordani, lati afonifoji Arnoni lọ dé òke Hermoni;

Deu 3

Deu 3:6-9