Deu 3:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo ilu wọnyi li a mọ odi giga si pẹlu ibode, ati idabu-ẹ̀kun; laikà ọ̀pọlọpọ ilu alailodi.

Deu 3

Deu 3:1-6