Deu 3:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBANA li awa pada, a si lọ soke li ọ̀na Baṣani: Ogu ọba Baṣani si jade si wa, on ati gbogbo awọn enia rẹ̀, fun ìja ni Edrei.

Deu 3

Deu 3:1-11