Deu 29:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si wipe, Nitoriti nwọn kọ̀ majẹmu OLUWA, Ọlọrun awọn baba wọn silẹ, ti o ti bá wọn dá nigbati o mú wọn lati ilẹ Egipti jade wá.

Deu 29

Deu 29:19-29