Deu 29:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

WỌNYI li ọ̀rọ majẹmu ti OLUWA palaṣẹ fun Mose lati bá awọn ọmọ Israeli dá ni ilẹ Moabu, lẹhin majẹmu ti o ti bá wọn dá ni Horebu.

Deu 29

Deu 29:1-7