Deu 27:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose ati awọn alufa awọn ọmọ Lefi si sọ fun gbogbo Israeli pe, Israeli, dakẹ, ki o si gbọ́; li oni ni iwọ di enia OLUWA Ọlọrun rẹ.

Deu 27

Deu 27:2-13