Deu 27:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o si ma ru ẹbọ alafia, ki iwọ ki o si jẹun nibẹ̀; ki iwọ ki o ma yọ̀ niwaju OLUWA Ọlọrun rẹ.

Deu 27

Deu 27:1-12