Deu 21:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ki awọn àgba rẹ ati awọn onidajọ rẹ ki o jade wá, ki nwọn ki o si wọ̀n jijìna awọn ilu ti o yi ẹniti a pa na ká.

Deu 21

Deu 21:1-12