Deu 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ máṣe bá wọn jà; nitoripe emi ki yio fun nyin ninu ilẹ wọn, ani to bi ẹsẹ̀ kan: nitoriti mo ti fi òke Seiri fun Esau ni iní.

Deu 2

Deu 2:1-6