Deu 15:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ki yio sí talaka ninu nyin; (nitoripe OLUWA yio busi i fun ọ pupọ̀ ni ilẹ na, ti OLUWA Ọlọrun rẹ fi fun ọ ni iní lati gbà a;)

Deu 15

Deu 15:1-7