Deu 14:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ọmọ Lefi ti mbẹ ninu ibode rẹ; iwọ kò gbọdọ kọ̀ ọ silẹ; nitoriti kò ní ipín tabi iní pẹlu rẹ.

Deu 14

Deu 14:19-29