Deu 14:10-12 Yorùbá Bibeli (YCE)

10. Ati ohunkohun ti kò ba ní lẹbẹ ti kò si ní ipẹ́, ki ẹnyin ki o máṣe jẹ ẹ; alaimọ́ ni fun nyin.

11. Gbogbo ẹiyẹ ti o mọ́ ni ki ẹnyin ki o ma jẹ.

12. Ṣugbọn wọnyi li awọn ti ẹnyin kò gbọdọ jẹ ninu wọn: idì, ati aṣa-idì, ati idì-ẹja.

Deu 14