Deu 1:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitõtọ ọkan ninu awọn ọkunrin wọnyi ti iran buburu yi, ki yio ri ilẹ rere na, ti mo ti bura lati fi fun awọn baba nyin,

Deu 1

Deu 1:29-37