Dan 7:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn onidajọ yio joko, nwọn o si gbà agbara ijọba rẹ̀ lọwọ rẹ̀ lati fi ṣòfo, ati lati pa a run de opin.

Dan 7

Dan 7:19-28