Dan 6:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni awọn ọkunrin wọnyi wipe, Awa kì yio le ri ẹ̀sùn kan si Danieli bikoṣepe a ba ri i si i nipasẹ ofin Ọlọrun rẹ̀.

Dan 6

Dan 6:1-7