Dan 6:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Dariusi, ọba kọwe si gbogbo enia, orilẹ, ati ède ti o wà ni gbogbo aiye pe, Ki alafia ki o ma bi si i fun nyin.

Dan 6

Dan 6:18-26