Dan 4:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ọ̀rọ na si ti wà lẹnu ọba, ohùn kan fọ̀ lati ọrun wá, pe, Nebukadnessari, ọba, iwọ li a sọ fun; pe, a gba ijọba kuro lọwọ rẹ.

Dan 4

Dan 4:28-36