Dan 4:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ami rẹ̀ ti tobi to! agbara iṣẹ iyanu rẹ̀ ti pọ̀ to! ijọba ainipẹkun ni ijọba rẹ̀, ati agbara ijọba rẹ̀ ati irandiran ni.

Dan 4

Dan 4:2-13