Dan 2:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li Arioku yara mu Danieli lọ siwaju ọba, o si wi bayi fun u pe, Mo ri ọkunrin kan ninu awọn ọmọ igbekun Juda, ẹniti yio fi itumọ na hàn fun ọba.

Dan 2

Dan 2:16-29