Dan 2:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O dahùn o si wi fun Arioku, balogun ọba pe, Ẽṣe ti aṣẹ fi yá kánkán lati ọdọ ọba wá bẹ̃? Nigbana ni Arioku fi nkan na hàn fun Danieli.

Dan 2

Dan 2:10-21