Dan 12:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn iwọ ma ba ọ̀na rẹ lọ, titi opin yio fi de, iwọ o si simi, iwọ o si dide duro ni ipo rẹ ni ikẹhin ọjọ.

Dan 12

Dan 12:8-13