Dan 11:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn on o lagbara lori iṣura wura, ati ti fadaka, ati lori gbogbo ohun daradara ni ilẹ Egipti: ati awọn ara Libia, awọn ara Etiopia yio si wà lẹhin rẹ̀.

Dan 11

Dan 11:39-45